Your feedback is important to us, send us your feedback today!

Mi o fE ki iyawomi ma se ise sugbon mofi aye gbaa lati ma mu ninun owo mi oun tomope koni pamara. Lati MA fi gbo bukata ti o be fe. Se eleyi o ba esin mu abi ona mi tunwa. Sugbon odun Kerin ni yi ti ati fera kosi wahalakankan Lori e.

Shaykh Sharafudeen Gbadebo Raji

Yoruba 4 years ago
00:00 / 00:00
AUTOPLAY